Ìwàtánnáyé
Sísọ síta
Ìtumọọ Ìwàtánnáyé
Good character has not disappeared from life.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ìwà-à-tán-ní-ayé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ìwà - characterà - one who; someone
tán - complete(ly), finish
ní - have
ayé - earth, world, life
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
AKURE
ONDO