Ìrọ̀rùnwánrí

Sísọ síta



Ìtumọọ Ìrọ̀rùnwánrí

Comfort/ease found me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ìrọ̀rùn-wá...rí-mi



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ìrọ̀rùn - ease, comfort, calm
wá...rí - seek out
mi - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL