Ìránládé
Sísọ síta
Ìtumọọ Ìránládé
Our lineage has a crown.
Àwọn àlàyé mìíràn
A child born in the lineage of a king, often times when their parent is the monarch or in the ruling house currently on the throne.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ìran-ní-adé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ìran - generation(s), genealogy, lineagení - to have
adé - crown, royalty
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL