Ìpínmoyè

Sísọ síta



Ìtumọọ Ìpínmoyè

Destiny knows honor.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ìpín-mọ-oyè



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ìpín - portion, destiny, fate
mọ - know, recognize
oyè - chieftaincy, honour


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI