Ìpínmorótì

Sísọ síta



Ìtumọọ Ìpínmorótì

I stand by (my) destiny.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ìpín-mo-ró-tì



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ìpín - portion, destiny, fate
mo - I
- stand (dúró)
- with


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI



Irúurú

Morótì