Ìlúsìnmí

Sísọ síta



Ìtumọọ Ìlúsìnmí

The town serves me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ìlú-sìn-mí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ìlú - town
sìn - worship, serve
- me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OYO



Irúurú

Sìnmí