Ìjàọlá
Sísọ síta
Ìtumọọ Ìjàọlá
The fight for wealth/honor.
Àwọn àlàyé mìíràn
This can also be interpreted as the struggle between parts of a notable family (resulted in this)
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ìjà-ọlá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ìjà - fight, struggleọlá - wealth, success, nobility, notability
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA