Ìjíyọkùnọlà

Sísọ síta



Ìtumọọ Ìjíyọkùnọlà

The act of waking up has brought forth wealth/riches.



Àwọn àlàyé mìíràn

Ijiyokunola means “waking up to wealth/affluence” It is an Ijesha name. - Samuel Ijiyokunola



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ì-jí-yọ-ikùn-ọlà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ì - the act of
- wake up
yọ - emerge, to grow
ikùn - belly (womb)
ọlà - wealth, luck, fortune


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ILESHA



Irúurú

Ìjíyọkùn