Ìjítọ́lá

Sísọ síta



Ìtumọọ Ìjítọ́lá

Waking up is equal to honor.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ì-jí-tó-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ì - the act of
- to wake up
- is enough for
ọlá - wealth/nobility/success/honor


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
AKURE



Irúurú

Tọ́lá