Ìjásúnmádé
Sísọ síta
Ìtumọọ Ìjásúnmádé
Ìja has drawn closer to royalty.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ìja-súnmọ́-adé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ìja - Ìja, deity of hunting, brother of Ògún and Ọ̀ṣọ́ọ̀sìsúnmọ́ - move close to
adé - crown, royalty
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OWO