Ìjámorótì
Sísọ síta
Ìtumọọ Ìjámorótì
Ìja is who I stand with.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ìja-mo-ró-tì
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ìja - Ìja, deity of hunting, brother of Ògún and Ọ̀ṣọ́ọ̀sìmo - I
ró - stand, wait (dúró)
tì - with, onto
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OWO