Ìjámákindé
Sísọ síta
Ìtumọọ Ìjámákindé
Ìja has brought a warrior here.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ìja-mú-akin-dé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ìja - Ìja, deity of hunting, brother of Ògún and Ọ̀ṣọ́ọ̀sìmú - take, pick, use
akin - valor, bravery, the brave one
dé - arrive
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI