Ìjágbọ́lágún

Sísọ síta



Ìtumọọ Ìjágbọ́lágún

Ìja has aligned honor.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ìja-gbé-ọlá-gún



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ìja - Ìja, deity of hunting, brother of Ògún and Ọ̀ṣọ́ọ̀sì
gbé - carry
ọlá - success, nobility, wealth
gún - set, to align, to be good.


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI



Irúurú

Gbọ́lágún