Ìjádélé

Sísọ síta



Ìtumọọ Ìjádélé

Ìja has arrived home.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ìja-dé-ilé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ìja - Ìja, deity of hunting, brother of Ògún and Ọ̀ṣọ́ọ̀sì
- arrive
ilé - home, house


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI
ONDO
OWO



Irúurú

Délé