Ìjábọ́rọ̀dé
Sísọ síta
Ìtumọọ Ìjábọ́rọ̀dé
Ìja arrived with riches.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ìja-bá-ọrọ̀-dé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ìja - Ìja, deity of hunting, brother of Ògún and Ọ̀ṣọ́ọ̀sìbá - together with, meet
ọrọ̀ - wealth, riches
dé - arrive
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OWO