Ìfẹ́jọlá

Sísọ síta



Ìtumọọ Ìfẹ́jọlá

Love is greater than honor.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ìfẹ́-ju-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ìfẹ́ - love
ju - more than
ọlá - wealth/nobility/success/honor


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ìfẹ́

Jọlá