Ìbùkúnọláolúwa
Sísọ síta
Ìtumọọ Ìbùkúnọláolúwa
The blessing(s) of God's honor/wealth.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ì-bù-kún-ọlá-olúwa
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ì - the act ofbù - to add to, to scoop
kún - in addition to, fulfillment
ọlá - honour, prestige, wealth, nobility
olúwa - lord, God
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL