Èdíléọlá

Sísọ síta



Ìtumọọ Èdíléọlá

(One of) an honorable lineage.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

èdílé-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

èdílé - household, clan, lineage (ìdílé)
ọlá - honour, nobility, wealth, success, prestige


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO