Èṣúgboùngbé
Sísọ síta
Ìtumọọ Èṣúgboùngbé
Èṣù has not allowed our voice to perish.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
èṣù-ò-gba-oùn-gbé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
èṣù - Èṣù, the deity of consequence, messengers, trickeryò - is not, does not
gba - to collect, to receive, to take
oùn - voice (ohùn)
gbé - to perish
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IJEBU