Èṣúdínà

Sísọ síta



Ìtumọọ Èṣúdínà

Èṣù blocked the road (of my enemies).



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

èṣù-dí-ọ̀nà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

èṣù - Èṣù, the deity of consequence, messengers, trickery
- to block
ọ̀nà - road, lane, way, path


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Èshúdínà

Dínà