Ẹ̀rùkúbàmí
Sísọ síta
Ìtumọọ Ẹ̀rùkúbàmí
Death does not scare me.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ẹ̀rù-ikú-ò-bà-mí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ẹ̀rù - fear, aweikú - death
ò - is not, does not
bà - to affect
mí - breathe
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ILAJE