Ẹ̀ríntáyọ̀mi

Sísọ síta



Ìtumọọ Ẹ̀ríntáyọ̀mi

Laughter is equal to my joy.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ẹ̀rín-tó-ayọ̀-mi



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ẹ̀rín - laughter
- suffice for, to be equal to, worthy
ayọ̀ - joy
mi - me, my


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Táyọ̀mi

Ẹ̀ríntáyọ̀

Táyọ̀