Sísọ síta
One cannot carry anything away from the world.
(w)ẹ́-ẹ̀-gbé-ayé-lọ
Ó pọ̀ ní: ONDO OKITIPUPA
Bóyá o tiẹ̀ ní ìtàn kan láti sọ fún wa nípa orúkọ yìí, tàbí fún wa ní ǹkan tí a ṣì kọ, tàbí fikún oun kan tí a kọ sílẹ̀.