Àyányẹmí

Sísọ síta



Ìtumọọ Àyányẹmí

Being a drummer befits me.



Àwọn àlàyé mìíràn

See also: Adéyẹmí, Oyèyẹmí, Olúyẹmí, Ọláyẹmí, etc



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

àyàn-yẹ-mí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

àyàn - the drummer
yẹ - befit, benefit
mí - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Yẹmí