Ṣónáìkè

Sísọ síta



Ìtumọọ Ṣónáìkè

The fertility god (Òrìṣà Oko) has become famous.



Àwọn àlàyé mìíràn

See also: Ṣónóìkí. ---- The root Oṣó in most Yorùbá names comes from the deity of farming and fertility called Òrìṣà Oko. But the word "Oṣó" also means the same as "wizard" or "sorcerer" which is the interpretation that most people, including the name's most famous ambassador (Wọlé Ṣóyínka), uses. Read more about the root of common Yorùbá names (and their mistranslations) here: https://www.facebook.com/agadeniran/posts/10206154527806205



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

(o)ṣó-ní-àìkè



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oṣó - sorcerer, god of fertility (Òrìṣà oko)
ní - have
àìkè - notability, fame (òkìkí)


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀



Ibi tí a ti lè kà síi



Irúurú

Oṣónáìkè, Shónáìkè



Ẹ tún wo