Ọyágbọlá

Sísọ sítaÌtumọọ Ọyágbọlá

Ọya received honour.Àwọn àlàyé mìíràn

See also: Adégbọlá, Oyègbọlá, OlúgbọláÌtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọya-gbà-ọláÌtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọya - the goddess Ọya
gbà - receive, accept
ọlá - honour, nobility


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL
IBADANÀwọn Ènìyàn Gbajúọ̀Ibi tí a ti lè kà síiIrúurú

GbọláẸ tún wo