Oníkẹ́kù

Sísọ síta



Ìtumọọ Oníkẹ́kù

1. There remains people to care (for me). 2. Someone with enough care to smother another to death. (Oníkẹ̀ẹ́kú) 2a. One's carer died.



Àwọn àlàyé mìíràn

As per the second meaning, we received this comment: "Actually I had a conversation with my Dad, and he actually explained that it is Oníkẹ́-kú (as in death) now it is in the explanation that it becomes interesting, it is not "the carer dies" but "one who cares too much" that is, ẹni tó lè kẹ́ èèyàn pa. Thanks for the great work you are doing on all our behalf. Best. Q"



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

oní-ìkẹ́-kù



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oní - the owner of
ìkẹ́ - care, doting, petting
kù - remain


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA



Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀

Qudus Oníkẹ̀ẹ́kú, Nigerian dance artist.



Ibi tí a ti lè kà síi

http://www.qudusonikeku.com/



Irúurú



Ẹ tún wo