Gbọ́lágadé

Sísọ sítaÌtumọọ Gbọ́lágadé

Put wealth on royalty.Àwọn àlàyé mìírànÌtúpalẹ̀ Mọ́fímù

gbé-ọlá-gùn-adéÌtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

gbé - carry
ọlá - wealth
gùn - climb
adé - crown


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERALÀwọn Ènìyàn Gbajúọ̀Ibi tí a ti lè kà síiIrúurú

Gbọ́lá, GadéẸ tún wo