Adéfowórà

Sísọ síta



Ìtumọọ Adéfowórà

The crown (child) that we got at great monetary cost.



Àwọn àlàyé mìíràn

"Fowórà" is usually given to children whose conception, pregnancy or birth was troublesome for the parents, and cost them a lot of money (for physicians). See also: Àyànfowórà, Oyèfowórà.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-fi-owó-rà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown, royalty
fi - use
owó - money, funds
rà - buy


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀

Ọba Adéyemí Adéfowórà Pastor Emmanuel O. Adéfowórà(Clergy)



Ibi tí a ti lè kà síi

http://guardian.ng/sunday-magazine/community-calls-for-monarchs-removal/ http://www.trinitylivingchurch.org/meet-pastor-emmanuel/



Irúurú

Fowórà



Ẹ tún wo