Ọmọ́goríọlá

Sísọ sítaÌtumọọ Ọmọ́goríọlá

The child is greater than wealth (riches).Àwọn àlàyé mìírànÌtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọmọ-gorí-ọláÌtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọmọ - child
gorí - climb, ascend, be on top of (be greater than)
ọlá - wealth, riches


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTAÀwọn Ènìyàn Gbajúọ̀Ibi tí a ti lè kà síiIrúurúẸ tún wo