Págà! A kò rí oun tó jọ "Yẹba"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Adéyẹba
Meaning: 1. The crown befits the king. 2. The one who arrived and befits the king.
Kúyẹ̀bà
Meaning: Death has been averted.
Mọ́ríyebá
Meaning: The child has (many) women at his/her back.
Ọmọ́ríyebá
Meaning: The child met his/her mother.
Oyèbádé
Meaning: A title of honor has met royalty.
Oyèbámbọ̀
Meaning: I came with title/honour.
Oyèbámijí
Meaning: Honour wakes up with me.
Oyèbámirẹ́
Meaning: Honour is related to me.
Oyèbámjí
Meaning: Honour woke up with me.
Oyèbándé
Meaning: Honour arrives with me.
Oyèbánjí
Meaning: Honour/Chieftaincy woke up with me.
Oyèbánjọ
Meaning: Honor is in agreement with me.