Págà! A kò rí oun tó jọ "Tódù"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Awótódù
Meaning: The Ifá priest is worthy of the Ifá corpus.
Fátódù
Meaning: (The child of) Ifá is as prominent as the odù.
Moróhuntódùn
Meaning: I have found something that's sweet.
Moróuntódùn
Meaning: I've found something sweet.
Ògúntódù
Meaning: Ògún is equal to the Ifá corpus.
Ọlọ́fíntódù
Meaning: Ọlọ́fin is equal to the Ifá corpus.