Págà! A kò rí oun tó jọ "Róunbí"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Fáróunbí
Meaning: Ifá found something (good) to birth.
Fátúróunbí
Meaning: Ifá has found something to give birth to again.
Ifáróunbí
Meaning: Ifa found (a child) to give birth to.
Ọdẹ́róunbí
Meaning: The hunter found someone (prominent) to birth.
Okùróunbí
Meaning: The deity of enterprise has given birth to a (decent) child.
Olúróunbí
Meaning: The prominent one found someone (prominent) to birth.
Olúrónbí
Meaning: The prominent one has found a (good) child to birth.