Págà! A kò rí oun tó jọ "Ráyọ̀"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Adéráyọ̀
Meaning: The crown has seen joy, One who arrives to meet joy
Atiráyọ̀
Meaning: We have found joy.
Farayọ́lá
Meaning: Rub off on success. Mingle with nobility/wealth.
Jíráyọ̀
Meaning: Wakes up to see joy.
Kòfowórayọ̀
Meaning: He/she didn't use money to buy happiness.
Modémoráyọ̀
Meaning: I came and I saw joy.
Mojíráyọ̀
Meaning: I woke up into joy.
Moráyọ̀
Meaning: I've found joy.
Motiráyọ̀
Meaning: I have seen joy.
Motúnráyọ̀
Meaning: I see joy again.
Motúráyọ̀
Meaning: I've seen joy again.
Ojúmiráyọ̀
Meaning: My eyes have seen joy.
Ojúmitúnráyọ̀
Meaning: My eyes have seen joy again.
Túnráyọ̀
Meaning: (I've) seen joy again.
Ẹgbẹ́bámiráyọ̀
Meaning: Ẹgbẹ́ spirit helps me find/see joy.
Ẹgbẹ́jẹ́nráyọ̀
Meaning: The Ẹgbẹ́ spirit allowed me find joy.
Ọdúnmoráyọ̀
Meaning: The year I experienced joy or happiness.
Ọmọ́jíráyọ̀
Meaning: The child wakes up to joy.
Ọ̀ráyọdé
Meaning: Ọ̀ràm̀fẹ̀ has emerged.
Motúnrọ́lá
Meaning: I've found success again.
Morífẹ̀ẹ́
Meaning: I've found love.
Moríre
Meaning: I've seen goodness.
Morádé
Meaning: I've found royalty.