Págà! A kò rí oun tó jọ "Léọlá"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Abíléọlá
Meaning: HOMOGRAPH 1. One given birth to after tremendous wealth (Abíléọlá. Also Àbíléọlá) 2. One given birth to in the home of wealth (Abíléọlá. e.g. A bí ní ilé ọlá)
Èdíléọlá
Meaning: (One of) an honorable lineage.
Ifáwáléọlá
Meaning: Ifá enters the house of affluence.
Irébọ́síléọlá
Meaning: Goodness has emerged in a house of honour.
Motẹlẹ̀ọlá
Meaning: I have stepped onto a ground/land of honor.
Oluwoleola
Meaning: 1. God walks into the house of honour. 2. The leader walks into a house of honour.
Ọmọ́gúléọlá
Meaning: The child has settled in an honorable house.
Ọmọ́tẹ́lẹ̀ọlá
Meaning: The child prepares the ground for wealth.
Ọmọ́wáléọlá
Meaning: A child came to a home of wealth.
Ọmọ́wọléọlá
Meaning: The child has entered a home of honor.
Tẹ̀léọlá
Meaning: Follow success/nobility/wealth.
Wáléọlá
Meaning: Enter into the house of wealth.
Wọléọlá
Meaning: Enter into the house of honour.