Págà! A kò rí oun tó jọ "Kànbí"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Adékànbí
Meaning: The crown deliberately birthed me.
Àkànbí
Meaning: One consciously, deliberately, born.
Akanbíẹmu
Meaning: As sour as palm wine.
Ayọ̀kànbí
Meaning: Joy deliberately gave birth to me.
Aṣàbí
Meaning: One selected for birth.
Àkànfẹ́
Meaning: Specially loved.
Adékàḿbí
Meaning: I was given birth to deliberately by royalty.