Págà! A kò rí oun tó jọ "Juyìgbé"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Adéjuyìgbé
Meaning: Royalty has prevented honour from being wasted/destroyed.
Awójuyìgbé
Meaning: Ifá did not allow honor to perish.
Fájuyìgbé
Meaning: Ifá did not let honour go to waste.
Ifájuyìgbé
Meaning: Ifá did not let honour go to waste.
Ògunjuyigbe
Meaning: Ògún does not let honour go to waste.
Ọlájuyìgbé
Meaning: Nobility will not let honour go to waste.
Olújuyìgbé
Meaning: The lord didn't let honour go to waste.
Olúwajuyìgbé
Meaning: God doesn't let honour go to waste.
Ọ̀rìṣájuyìgbé
Meaning: Òrìṣà did not allow (my) honor to perish.
Olú
Meaning: 1. The head. 2. The prominent one. 3. The lord. 4. God (olúwa) 5. The hero/champion
Fajoyègbé
Meaning: Ifá does not let honour go to waste.
Ifájuyìtán
Meaning: Ifá would not let honour finish.
Fájùlúgbé
Meaning: Ifá did not let the town go to waste.
Ògúnjádégbé
Meaning: Ògún did not allow royalty to perish (in our lineage).