Págà! A kò rí oun tó jọ "Dùnmọ́lá"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Adédùnmọ́lá
Meaning: Royalty is sweet with nobility.
Ẹgbẹ́dùnmọ́lá
Meaning: Ẹgbẹ́ is sweet with wealth/nobility/success.
Èwédùnmọ́lá
Meaning: Youth is sweetened with honour or wealth.
Ọmọ́dùnmọ́lá
Meaning: A child is sweet with wealth.
Oyèdùnmọ́lá
Meaning: Royalty is sweet with affluence.
Oyíndùnmọ́lá
Meaning: Honey is sweet when paired with wealth.