Págà! A kò rí oun tó jọ "Dùní"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Àdùní
Meaning: 1. A joy to have. 2. One we struggled to have.
Àdùníadé
Meaning: One very sweet to have.
Adùniyì
Meaning: The sweetness of honour.
Ìbídùní
Meaning: (Good) pedigree is good to have.
Ìyádùní
Meaning: Mother is worth having. Mother is delightful to have.
Ọdúnifá
Meaning: The festival of Ifá. The year of Ifá. The season of Ifá.
Ọdúnìtàn
Meaning: The year, festival, of stories, of history.
Ọládùní
Meaning: Wealth is sweet to have.
Ìyádùnní
Meaning: Mother is sweet to have.