Págà! A kò rí oun tó jọ "Dipúpọ̀"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Ayọ̀dipúpọ̀
Meaning: Joy becomes plenty.
Ládipúpọ̀
Meaning: Wealth has increased.
Ọládipúpọ̀
Meaning: Wealth has become many.
Ọlámidipúpọ̀
Meaning: My joy has multiplied.
Oyèdipúpọ̀
Meaning: Chieftaincy is multiplied.
Tèmídipúpọ̀
Meaning: Mine has became abundance
Ládi
Meaning: A shortened form of "Oladipúpọ" or "Ọládiméjì" or "Ládiípọ̀"
Ọládipípọ̀
Meaning: Honour has multiplied. See: Ọládipúpọ̀ and Ọládiipọ̀.
Ládípọ̀
Meaning: Wealth/Nobility/Success becomes plenty.