Págà! A kò rí oun tó jọ "Dìmú"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Fádìmúlà
Meaning: Ifá, one to hold onto in order to survive.
Fámodìmú
Meaning: Ifá is what I'm holding onto.
Fátúdìmú
Meaning: Ifá is worth holding onto.
Ọbádìmú
Meaning: The king holds.
Ògúndìmú
Meaning: Ògún holds onto (him/her/us)
Ògúnmodìmú
Meaning: It is Ògún that I hold onto.
Olúdìmú
Meaning: The lord holds.
Olúmodìmú
Meaning: The lord it is that I hold onto.
Olúwatódìmú
Meaning: God is worth holding onto. God is worthy of being held onto.
Shódìmú
Meaning: The god of fertility holds (him/her/us).
Ṣódìmú
Meaning: The sorcerer upheld.
Tódìmú
Meaning: Enough to hold on to.
Olú
Meaning: 1. The head. 2. The prominent one. 3. The lord. 4. God (olúwa) 5. The hero/champion
Ọlọ́fínghàká
Meaning: Ọlọ́fin is everywhere.