Ọṣíyọyè
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọṣíyọyè
The Ọṣìn deity has emerged into a position of honour.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọṣìn-yọ-oyè
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọṣìn - Ọṣìn deity; king, leaderyọ - emerge, to grow
oyè - honour, chieftaincy
Agbègbè
                        Ó pọ̀ ní:
                            
OGUN                            
IJEBU                    
