Ọshìfẹ̀sọ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọshìfẹ̀sọ̀

Ọṣìn uses calm (to live).



Àwọn àlàyé mìíràn

Probably a shortening of Ọshìfẹ̀sọ̀jayé, "Ọṣìn uses calm to enjoy life." See Ọṣìfẹ̀rọ̀.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọṣì-fi-ẹ̀sọ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọṣì - king, Ọṣì deity (ọṣìn)
fi - use (it/him/her)
ẹ̀sọ̀ - gentility, cunning, calm


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IJEBU



Irúurú

Ọṣìfẹ̀sọ̀

Ọṣìnfẹ̀sọ̀

Fẹ̀sọ̀

Fẹ̀sọ̀jayé