Ọnàṣẹ̀ṣọ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọnàṣẹ̀ṣọ́
Art has created jewelry/adornments.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọnà-ṣe-ẹ̀ṣọ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọnà - artistryṣe - make
ẹ̀ṣọ́ - guard (ọ̀ṣọ́/ẹ̀ṣọ́), protector, warrior, adornment
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IJEBU