Ọláloyè
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọláloyè
Nobility is chieftaincy. Wealth is chieftaincy.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọlá-ni-oyè
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọlá - wealth, nobility, successni - is
oyè - honour, chieftaincy
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL
Irúurú
Professor Moṣọbalájé Ọláloyè Ọyáwọyè (1927-2023) Professor of Geology.