Ọbátẹ́níọlámi

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọbátẹ́níọlámi

The king parades my honour/prestige (for the world to see).



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọba-tẹ́-ẹní-ọlá-mi



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọba - king, God, Ọbalúayé
tẹ́ - spread
ẹní - mat, carpet
ọlá - wealth, success, prestige, nobility, honour
mi - mine


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Tẹ́níọlá