Ẹfúnyanjú
Sísọ síta
Ìtumọọ Ẹfúnyanjú
Purity is complete.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ẹfun-yanjú
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ẹfun - chalk, purity, whiteness; symbol of the deity Ọbàtáláyanjú - to complete, to finish, to succeed
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL