Ṣọpẹ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Ṣọpẹ́

Be grateful. Be thankful. Give thanks.



Àwọn àlàyé mìíràn

See: Adéṣọpẹ́, Moṣọpẹ́, Moṣọpẹ́fólúwa, Olúṣọpẹ́, etc



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ṣẹ-ọpẹ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ṣẹ - happen; to come true
ọpẹ́ - praises/thanksgiving


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Shọpẹ́