Ṣólànà
Sísọ síta
Ìtumọọ Ṣólànà
The sorcerer opened the path.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
oṣó-la-ọ̀nà
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
oṣó - sorcererlà - open
ọ̀nà - path, road
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OGUN
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Dúpẹ́ Ṣólànà (famous gospel musician)