Ògúnmilọ́rọ̀

Pronunciation



Meaning of Ògúnmilọ́rọ̀

My Ògún has riches.



Morphology

ògún-mi-ní-ọrọ̀



Gloss

ògún - Ògún, Yorùbá god of iron, war, hunting, and technology
mi - me
- have, own; into
ọrọ̀ - wealth, riches


Geolocation

Common in:
EKITI



Variants

Milọ́rọ̀